OweYoruba Logo OweYoruba
StoreBlogAdvertise
Log in →

Over 0 Yoruba Proverbs and Counting... 🚀

Largest collection of Yoruba proverbs online.

Want to contribute? Add a new proverb →

📌 Latest Additions

Rọra dì, ká lè bá ọ sá

Sùúrú loògùn ayé

Ìwà lẹwà

Wọ́n ṣe bí òtòṣì ò gbọ́n bí ọlọ́rọ̀; wọ́n ní ì bá gbọ́n ì bá lówó lọ́wọ́.

Dídùn ló dùn tí à ńbọ́rẹ̀-ẹ́ jẹ̀kọ; tilé oge-é to oge-é jẹ

🌟 Most Popular

Dídùn ló dùn tí à ńbọ́rẹ̀-ẹ́ jẹ̀kọ; tilé oge-é to oge-é jẹ

Alájọbí ò sí mọ́, alájọgbé ló kù

Sùúrú loògùn ayé

Rọra dì, ká lè bá ọ sá

© 2024 oweyoruba.com